Tubokosemie Abere


Tubokosemie Aberei[1] (ti abi ni ọjọ keji di logun oṣù kẹjọ ọdún 1950) o jẹ oṣiṣẹ feyinti Anglican bishopNigeria:[2] o jé Bishop of Okrika, ọkàn nínú mẹsan Anglican Province of the Niger Delta, ẹyà kàn lara merinla Ninu Church of Nigeria.[3]


A yà sí mímọ gẹgẹ bi aṣáájú-ọnà Bishop tí Okrika at St. Cyprian's Church, Port Harcourt ni ọjọ kerindinlogun oṣù kọkànlá ọdún 2003[4] a sì jọba lórí rẹ ní ọdún 2004.[5] o feyinti ni ọdún 2020.[6]

Notes


This article is issued from Wikipedia. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.